Tope Alabi – Oluwa O Tobi
Oluwa O Tobi by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Oluwa O Tobi. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics Of Oluwa O Tobi by Tope Alabi
Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi Oluwa Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi Oluwa O tobi o, Oluwa giga lorile ede gbogbo Gbigbega ni O, Iwo lo logo ni orun Pupopupo ni O, O koja omi okun at’osa, O ga po Ajulo O o se juloOluwa o tobi, O tobi o, O tobi
Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi Oluwa Oba lori aye, O tobi o eh Agba’ni loko eru, Olominira to n de’ni lorun O fi titobi gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka Olugbeja mi to ba mi r’ogun lai mu mi lo t’o segun Akoni ni O o Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi Oluwa B’O ti tobi to oo, laanu Re tobi B’O ti tobi se o, ododo Re tobi o O tobi tife tife, Oni majemu ti kii ye Aro nla to gbo jije mimu aye gbogbo alai le tan Ogbon to koja ori aye gbogbo ooo Oluwa o tobi, O tobi o, O tobi Ko s’eni t’a le fi s’afiwe Re o, O tobi Ko s’eda t’a le fi s’akawe Re o, O tobi Oluwa Akoko O tobi, O tobi o Oluwa Ipilese ogborin o yeye O tobi Ibere Eni to f’ogbon da ohun gbogbo Oluwa Igbeyin ola nla, o la la oo O tobi Opin aye a’torun ko si ‘ru Re Oluwa O tobi, O o se s’akawe lailai o O tobi Agbaagba merinlelogun nki O, O tobi Oluwa Awon angeli won n ki O, O tobi O tobi Olorun Elijah Ireti Ajanaku Oluwa O ma tobi laye mi, O tobi ooo O tobi Iwo lo gb’orin t’O o ga, t’O gun, t’O tun fe Oluwa O ga, O gun, O fe, O jin, O tobi la la O tobi