Tope Alabi – Oba Aseda
Oba Aseda by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Oba Aseda. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics of Oba Aseda by Tope Alabi
A toto n to Olodumare, Olorun ogo,
Iba Re, Iba o, Akoda aye, Iwo nikan lo to, iba! A de’da, a m’eda Oba Alamo to mo ‘ponri eda o Akoko orun on aye Opo kan a gbamu aye o Ogo ni mo wa yin o o Oba Kabiyesi Re, Olorun toto Ogo, yeeee, ogo Akoko ade Iwo loba Omimi aye ti o le mi lailai o Olu inu awon orun Asaya apesin asako Iwo to tobi ju o lorun O f’aye s’apoti itise lasan Ogo, yeeee, ogo Ogo ye o, yeeeee ogo Olorun agbaye, mo f’ogo fun O ooo Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Iwo lajulo ti o see julo, mo f’ogo fun O Baba Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Atetekose Adiitu Oro, mo f’ogo fun O Baba Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Alapanla to so’le aye ro, mo f’ogo fun O ooo Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Iwo ni ‘gunwa ogo ti o lafiwe, mo f’ogo fun O Oba nla Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Awari Re aimo ni f’aye at’orun Ipa o to ju gbogbo ipa lo Angeli o le s’akawe ogo Re Didan ninu ewa at’orun d’orun O da’ye k’ohunkohun to d’aye Akoko k’angeli orun to wa Iwo to n s’ohun to tobi ju awari lo Owo ogo to f’ara s’ohun gbogbo logo Ogo yeeeee ogo Iba o, yeeeee iba o Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o Olorun agbaye, mo f’ogo fun O ooo Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Erujeje Arugbo Ojo, Agba lailai on lo je Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Olurapada wa, Ododo to n tan ‘mole Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Oba t’aa bi, sugbon ti a ko da Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Ilekun to ti mo iku, Kokoro si iye ayeraye Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O You are the Might above all mights Angels count Your glory, incomparable Shining in beauty from heaven to heaven, Creator of eternal things You are the first, before the heavenly angels You bigger than searchable Glorious and stylishly working all glory Glory Oh Glory (Ogo ogo) Unquestionable Great King, be Thou glorified Daddy Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Awon angeli juba Re, lojoojo o lorun Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Embodiment of wisdom and power You are Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Agbaagba lorun juba Re, won fi’ba yi O ka Baba Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Worker of numerous wonders, worshipped in trembling Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Gbogbo aye mi ni mo fi juba Re, gba ogo lori mi o Baba Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O You are the King Creator, be Thou glorified Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Ola ododo lo to si ‘Wo nikan nikan o Iwo loba Aseda, mo f’ogo fun O Iba Re Olorun o, Oba ayeraye e Kabiyesi Re o, Iwo nikan lola ododo to si Mo wa juba Re o, Iwo nikan lola ododo to si o