PraiseZion Blog



HOME |   |  OPPORTUNITIES |  SERMONS
|  JOBS |  INSTRUMENTAL | MIXTAPES |  DEVOTIONAL

SEARCH CONTENTS (Use Name Or Title)


Tope Alabi – Mo Taka Osi Danu

Mo Taka Osi Danu by Tope Alabi Mp3 Download

Download this track by Tope Alabi titled Mo Taka Osi Danu. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.

Use the link below to stream and download the song.

Lyrics Of Mo Taka Osi Danu by Tope Alabi

Motaka òsi dànù (mọ taka)Ẹ’mí taka òsì dànù (mọ taka)Òsi kó máa yá ilé míKi ń má rín na kàn òsiÒsi ki ń ṣe òun réré, mọ taka
Mọ taka ìyà dànù (mọ taka)Èmi taka ìyà dànù (mọ taka)Ìyà kọ má jẹ mí oKi ń má rìn ná jẹ ìyàÌyà kí n ṣe omi ọbẹ’ o, mọ taka
Ẹni tó fẹ irẹ, kò ná ọwọIrẹ wun èmi ní témiAyé tí mọ wá, kí má jìyà, ki ń má rìna kàn òsìỌlọrun to dà mí, kò dà mí fún ìyàKi ń má fí ìyà jẹ ‘ra míÌjáde, ìwọlé, àtilọ, àtibó, irẹ re kò má wo tèmi o
Mọ taka òfo dànù (mọ taka)Èmi taka òfo dànù (mọ taka)Òfo kò ṣe mí o (kò ṣe mí)Ki ń má ṣe òfo láyé mí o (ki ń má s’òfo, t tọmọ-tọmọ)Òfo ki ń ṣẹ òun réré, mọ taka
Òfo àdánù àti òfo orí mí ko, mọ taka ẹ sọnùKi ń n má sunkún, ki ń má fí Ìka bonu, ko má bo bàtà òfo sí ilé míKi ń má ká wo lerí, fẹsẹ jan lè, láyé tí mọ wáKo mamá péjọ bá mí daro, ko fo má ṣe mí (òfo ki ń ṣe tèmi)
Mọ taka àìsàn dànù (mọ taka), (lórúko Jésù o)Èmi taka werey dànù (mọ taka)Àìsàn kò má ṣe mí pa, ki ń má-má lọ sí werey (ko má fí kàn mí)Àìsàn kin se òun rere, (lórúko Jésù) mo taka
Gbogbo ọjọ’ lọ burú, àdúrà lọ ra ìgbà padàKi ma s’àìsàn, ká ṣọ bora, òtútù nígbà ọrùnK’orí mí má ṣe daru, ki ń má yá werey ọ’sán ganganKò má sọ mí mọ’lẹ’, k’àìsàn má pami sì àyídá laiyé mí (laiyé tí mò wá)
Ema gbàdúrà (e má gbàdúrà o)Ema gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)Ká má tó shi, ká má jìyà (e má gbàdúrà o)Ayé burú ma, fi inú to ni (e má gbàdúrà o)Ẹnì tó sumo ní gangan lè ṣeni (e má gbàdúrà o)Ìgbà òun lóko ènìyàn lọ ṣeyàn (e má gbàdúrà o)Ibi ilé ayé lo, kò má ye mí o (e má gbàdúrà o)Asorowa, ẹ jẹ ká ṣe dada (e má gbàdúrà o)
Ẹniti o fẹ òsì kò má fọwọ fàá òsì (e má gbàdúrà o)Ke má torí òun ayé ká wá di werey (e má gbàdúrà o)Ká má fo’wọ ará wá bá ayé ará wá jẹ (e má gbàdúrà o)Ká má gbèrò òfo s’èniyàn, ko fo má ṣe wá (e má gbàdúrà o)Torí a óò lè wá nínú ẹsẹ’, ẹ gbo (e má gbàdúrà o)Àní K’ ọrẹ ọ’fẹ’ o má posí (e má gbàdúrà o)Ọlọ’run o se ibi, eniyan ni ka bi (e ma gbàdúrà o)
Ẹ má gbàdúrà o (e ma gbàdúrà o)Ẹ dè má fí ìyè sínú (e má gbàdúrà o)Ẹ má gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)Ẹ má gbàdúrà o (e má gbàdúrà o)

DOWNLOAD MP3 HERE

| Categories: Gospel

CLICK HERE TO COMMENT ON THIS POST

WE ARE ON SOCIAL MEDIA

Facebook | Twitter | Instagram | Youtube

0 Comments

LEAVE A COMMENT

Type Name Below

Type Comment Below

« | »