Tope Alabi – Jesu Ore Otito
Jesu Ore Otito by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Jesu Ore Otito. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics Of Jesu Ore Otito by Tope Alabi
Wa s’ọdọ rẹ yìí o gba ọ
Oun nìkan ni Imọle tó ń tàn ṣókùnkùn Ọ’rọ’ rẹ iye ó ń gba ni’la Ko tún s’ónà mirán tó lè gbà níJésù, Jésù ọ’rẹ’ òtítọ’
Jésù Kristi ìyé l’ọrọ rẹ Òun tán mọ’lẹ’ ṣókùnkùn ayé wà Ẹni tó gbà Jésù lo ni ìyéWá má sọnù àiyé jìnà
Òun nìkan ló lè rìn ọ sí’èbúté Ààyè ṣókùnkùn, Jésù ni Imọle Gba gbó yóò mú ọ dé bi’sinmiJésù, Jésù ọ’rẹ’ òtítọ’
Jésù Kristi ìyé l’ọrọ rẹ Òun tán mọ’lẹ’ ṣókùnkùn ayé wà Ẹni tó gbà Jésù lo ni ìyéFà ayé rẹ fún, fọkàn rẹ fún
Má ṣe jẹ k’ọna rẹ mọ l’ójú rẹ Oluwa n kan ilekun, ore mase aya Ayọ’ là o fi bá Jésù jọbaJésù, Jésù ọ’rẹ’ òtítọ’
Jésù Kristi ìyé l’ọrọ rẹ Òun tán mọ’lẹ’ ṣókùnkùn ayé wà Ẹni tó gbà Jésù lo ni ìyéÒun adùn ni kí ẹrú wiwo di ìtàn
Àlàáfíà tí ayé kò rí ní Ifọkanbalẹ, irọrun èyí tó l’ogo La jogún f’àwọn t’oluwa gbà làJésù, Jésù ọ’rẹ’ òtítọ’
Jésù Kristi ìyé l’ọrọ rẹ Òun tán mọ’lẹ’ ṣókùnkùn ayé wà Ẹni tó gbà Jésù lo ni ìyeẸni tó gbà Jésù lo ni iye
Ẹni tó gbà Jésù lo ni iye