Tope Alabi – Fimi Dara Ire
Fimi Dara Ire by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Fimi Dara Ire. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics of Fimi Dara Ire by Tope Alabi
Olorun ara
S’aye mi ni re
Fimi dara to da Baba oo
Olorun ara
Oni’nu are
Fimi dara to wunmi ooo
Olorun Ara
S’aye mi logo
Fimi dara to da Baba oo
Olorun Ara
Oni’nu Ara
Fimi dara to wunmi ooo
Oba tomomi
Tonimi, todami ooo
Alara oni sababi
Wa S’aye mi nire
Mo fowo mi gba’rimi mu oo
Sanu Ori mi
Mo fowo mi gba’rimi mu oo
Wa sanu ori mi
Olorun ara
S’aye mi ni re
Fimi dara to da Baba oo
Olorun ara
Oni’nu ara
Fimi dara to wunmi ooo
Olorun ara
S’aye mi logo
Fimi dara to da Baba oo
Olorun Ara
Oni’nu Ara
Fimi dara to wunmi ooo
Iwo lo da da daa
To da ohun gbogbo saye
Odani to momi ooo
Kima waye wa jiya
Edu’a Olohun gbogbo lowo
Seke mi o Baba
Akan ii kere ainile Lori
Aja ikere ee gbigbo
Ologbo ii kere a n leku paje
Maje n kere si’re owo re
Kin se rere laye
Kima seru egbe mi o
Kima waye wa woran
Kint’egbe mi o
Kin tun jogba lo
Waa ‘bukun f’emi ooo
Olorun ara
S’aye mi ni re
Fimi dara to da Baba oo
Olorun ara
Oni’nu ara
Fimi dara to wunmi ooo
Olorun ara
S’aye mi logo
Fimi dara to da Baba oo
Olorun ara
Oni’nu ara
Fimi dara to wunmi ooo
Oba Alara, Oni’nu ara
Babara Ara n be lowo re
Eni to ku O ku Lofi dara ti o to oo
Wafimi da repete ara nla
Awimayehun oo
Eleberu Ike, Fimi dara to wunmi oo
Mikili ko o ku ofi dara ti o daa oo
Nebuchadnezari gberaga
Ofi dara ti o wun oo
Olorun ara
S’aye mi ni re
Fimi dara to da Baba oo
Olorun ara
Oni’nu ara
Fimi dara to wunmi ooo
Olorun ara
S’aye mi logo
Fimi dara to da Baba oo
Olorun Ara
Oni’nu ara
Fimi dara to wunmi ooo
S’anu aye mi o Baba
Eni to ba fi dara ire
Kii fara sinu ku
Jekara ayemi kowu egbe mi o
Alara topo, Onike ara
Fi mi dara to wu aye mi
Apesin ola, Oba nla
Adagagede onilekun ore
Apela oloro to po
Onire Jan ran abani mayo
Wa fa ye mi dara ire
Olorun ara
Oni inu ara
Fimi dara to wunmi ooo
Agbalagba oro
Oni bu Ola
Kiki da ara ni ofi da orun
Ara nla to da aye
Opolopo oro
Ingbala Ola la
Aje ori oro
Ileke Ibikun
Oni opa ara
Olorun akoda ola
Ijinle oro to ga, ga, ga
Alara to po o
Ma fi mi da ara ti ko da
Baba alara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire
Wa fi mi dara ire