Tope Alabi – Eru Re To Ba
Eru Re To Ba by Tope Alabi Mp3 Download
Download this track by Tope Alabi titled Eru Re To Ba. Tope Alabi is a Nigerian gospel singer, film music composer and actress. She hails from Yewa in Ogun State. Alabi developed an interest in music at a young age, participating in her church choir and singing during school events.
Use the link below to stream and download the song.
Lyrics of Eru Re To Ba by Tope Alabi
Erure to ba oo
Erure to ba oo
Oba to s’oro ti ina yo
Erure to ba oo
Erure to ba oo
Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo
Erure to ba oo
Erure tooo ba
Erure too ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo
Erure to ba oo
chorus
Olorun to s’oro ti ina yo
Erure to ba oo
Iwo to s’oro ti okun pupa gbe o
Erure to ba oo
Iwo to s’oro tokun pupa La oo
Erure to ba oo
Iwo to s’oro ti ina yo
Erure to ba oo
Iwo to s’oro ti ina yo oo
Erure to ba oo
Iwo to fi idin je odindi oba
Erure to ba oo
Erure to ba olorun oo
Erure to ba oo
Ah ah
chorus
Iwo to so Estheri d’ayaba lojiji
Erure to ba oo
O mu eru kuro laarin eru
O wa so eru d’oba ti gbogbo aye n wari fun
Erure to ba ooo
Olorun to s’oro ti ina yo o
Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo o
Erure to ba oo
Eleda to s’oro ti ina jade
Erure to ba oo
O mu omi jade ninu apata wa
Ta lo da bi re o
Erure to ba oo
chorus
O se oun t’enikan o le se aye raye
Erure to ba oo
Olorun to s’oro ti ina yo o
Erure to ba oo
Olorun to tun aye awa naa se
Erure to ba oo
Eni ta ti ro pe ko le pa go wa deni to kole ala ruru aah ha
Erure to ba oo
chorus
Aya re too ja yan
Aya re too ja yan olori aye
Erure to ba oo
Ooh Aya re ja mi yee ye
Erure to ba oo
Ogo re yio po oooo
Erure to ba oo
Erure to ba oooo
Erure to ba oo
Eru re to ba oooooo
Erure to ba o
outro
Erure to ba oo
Erure to ba oo